Àìsáyà 47:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú òkúta-ọlọ kí o sì lọ ìyẹ̀fun;mú ìbòjú ù rẹ kúrò.Ká yẹ̀rì rẹ sókè, kí o hó ẹṣẹ̀ rẹ sílẹ̀,kí o sì la inú odò lọ.

Àìsáyà 47

Àìsáyà 47:1-6