Àìsáyà 41:27-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó sọ fún Ṣíhóńì pé,‘Wò ó, àwọn nìyìí!’Mo fún Jérúsálẹ́mù ní ìránṣẹ́ ìhìn ayọ̀ kan.

28. Èmi wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan—kò sí ẹnìkan nínú wọn tí ó lè mú ìmọ̀ràn wá,kò sí ẹnìkan tí ó lè dáhùn nígbà tí mo bi wọ́n.

29. Kíyèsí i, irọ́ ni gbogbo wọn!Gbogbo ìṣe wọn já sí asán;àwọn ère wọn kò ṣé kò yà fúnafẹ́fẹ́ àti dàrúdàpọ̀.

Àìsáyà 41