Àìsáyà 40:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwayóò tún agbára wọn ṣe.Wọn yóò fìyẹ́ fò lókè bí idì;wọn yóò ṣáré àárẹ̀ kò ní mú wọn,wọn yóò rìn òòyì kò ní kọ́ wọn.

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:25-31