Àìsáyà 41:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wò, ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan—kò sí ẹnìkan nínú wọn tí ó lè mú ìmọ̀ràn wá,kò sí ẹnìkan tí ó lè dáhùn nígbà tí mo bi wọ́n.

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:21-29