2 Sámúẹ́lì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méfibóṣétì sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù: òun a sì máa jẹun nígbà gbogbo ní ibi oúnjẹ́ ọba; òun sì yarọ ní ẹṣẹ̀ rẹ̀ méjèèjì.

2 Sámúẹ́lì 9

2 Sámúẹ́lì 9:4-13