2 Sámúẹ́lì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe lẹ́yìn èyí, ọba àwọn ọmọ Ámónì sì kú, Hánúnì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 10

2 Sámúẹ́lì 10:1-4