2 Sámúẹ́lì 9:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méfibóṣétì sì ní ọmọ kékeré kan, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Míkà. Gbogbo àwọn tí ń gbé ní ilé Síbà ni ó sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún Méfibóṣétì.

2 Sámúẹ́lì 9

2 Sámúẹ́lì 9:4-13