2 Sámúẹ́lì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ogun náà sì pẹ́ títí láàrin ìdílé Ṣọ́ọ̀lù àti ìdílé Dáfídì: agbára Dáfídì sì ń pọ̀ si i, ṣùgbọ́n ìdílé Ṣọ́ọ̀lù ń rẹ̀yìn si i.

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:1-7