2 Sámúẹ́lì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì bí ọmọkùnrin ní Hébírónì: Ámónì ni àkọ́bí rẹ̀ tí Áhínóámù ará Jésírẹ́lì bí fún un.

2 Sámúẹ́lì 3

2 Sámúẹ́lì 3:1-6