2 Sámúẹ́lì 2:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n si gbé Ásáhélì wọ́n sì sinín sínú ibojì baba rẹ̀ tí ó wà ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù. Jóábù àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ fi gbogbo òru náà rìn, ilẹ̀ sì mọ́ wọn sí Hébírónì.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:31-32