2 Sámúẹ́lì 23:35-37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

35. Hésiráì ará Kérímélì,Páárì ará Áríbà;

36. Ígálì ọmọ Nátanì ti Sóbà,Bánì ará Gádì;

37. Sélékì ará Ámónì,Náhárì ará Béérótì, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Sérúíà;

2 Sámúẹ́lì 23