2 Sámúẹ́lì 23:29-34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Hélébù ọmọ Báánà, árá Nétófà,Íttaì ọmọ Ríbáì to Gíbéà ti àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì;

30. Bénáyà ará Pírátónì,Hídáyì tí àfonífojì.

31. Ábíálíbónì ará Áríbà,Ásámífétì Báríhúmítì;

32. Élíáhíbà ará Sáálíbónì,Jáṣénì Gísónítì,Jónátanì;

33. Ṣámà ará Hárárì,Áhíámù ọmọ Ṣárárì ará Hárárì;

34. Élífélétì ọmọ Áhásibáyì, ọmọ ará Máákíhà,Élíámù ọmọ Áhítófélì ará Gílónì;

2 Sámúẹ́lì 23