2 Sámúẹ́lì 23:24-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ásáhélì arákùnrin Jóábù sì Jásí ọ̀kan nínú àwọn ọgbọ̀n náà;Élíhánánì ọmọ Dódò ti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù;

25. Ṣámà ará Háródì,Élíkà ará Háródì.

26. Hélésì ará Pálitì,Irá ọmọ Íkéṣì ará Tékóà;

27. Ábíésérì ará Ánétótì,Móbúnnáì Húṣátítì;

2 Sámúẹ́lì 23