2 Sámúẹ́lì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì wí fún un pé, “Ìwọ kì yóò mù ìhìn lọ lónìí, ṣùgbọ́n ìwọ ó mú lọ ní ijọ́ mìíràn: ṣùgbọ́n lónìí yìí ìwọ kì yóò mú ìhìn kan lọ, nítorí tí ọmọ Ọba ṣe aláìsí.”

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:16-22