2 Sámúẹ́lì 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhímásì ọmọ Sádókù sì wí pé, “Jẹ́ kí èmi ó súré nísinsin yìí, kí èmi sì mú ìhìn tọ ọba lọ, bí Olúwa ti gbẹ̀san rẹ̀ lára àwọn ọ̀ta rẹ̀.”

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:18-25