2 Sámúẹ́lì 18:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì wí fún Kúṣì pé, “Lọ, kí ìwọ ro ohun tí ìwọ rí fún ọba.” Kúṣì sì wólẹ̀ fún Jóábù ó sì sáré.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:14-22