2 Sámúẹ́lì 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì jáde, gbogbo ilé rẹ̀ sì tẹ̀lé e. Ọba sì fì mẹ́wàá nínú àwọn obìnrin rẹ̀ sílẹ̀ láti máa sọ́ ilé.

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:15-18