2 Sámúẹ́lì 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì jáde, gbogbo ènìyàn sì tẹ̀lé e, wọ́n sì dúró ní ibìkan tí ó jìnnà.

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:9-20