2 Sámúẹ́lì 14:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì tọ ọba wá, ó sì rò fún un: ó sì ránṣẹ́ pe Ábúsálómù, òun sì wá sọ́dọ̀ ọba, ó tẹríba fún un, ó sì dojú rẹ̀ bolẹ̀ níwájú ọba, ọba sì fi ẹnu ko Ábúsálómù lẹ́nu.

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:28-33