2 Sámúẹ́lì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú ọkàn lè, jẹ́ kí a ṣe onígboyà nítorí àwọn ènìyàn wa, àti nítorí àwọn ìlú Ọlọ́run wa; Olúwa yóò sì ṣe èyí tí ó dára lójú rẹ̀.”

2 Sámúẹ́lì 10

2 Sámúẹ́lì 10:10-16