2 Sámúẹ́lì 10:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù àti àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ sì bá àwọn ará Síríà pàdé ìjà: wọ́n sì sá níwájú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 10

2 Sámúẹ́lì 10:12-18