2 Sámúẹ́lì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀yin òkè Gílíbóà,kí ẹ̀yin kí ó má ṣe rí ìrì tàbí òjò,tàbí oko tí ó mú èso ọrẹ wá.Nítorí ibẹ̀ ni aṣà alágbára ti ṣègbé,aṣà Ṣọ́ọ̀lù, bí ẹni pé a kò fi òróró yàn án.

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:19-27