2 Sámúẹ́lì 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọrun Jónátánì kì í padàbẹ́ẹ̀ ni idà Ṣọ́ọ̀lù kì í padà lásán,láì kan ẹ̀jẹ̀ àwọn tí a pa,àti ẹran àwọn alágbára.

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:16-27