2 Sámúẹ́lì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ má ṣe sọ ọ́ ní Gátì,ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní òpópónà Áṣíkélónì,kí àwọn ọmọbìnrin Fílístínì má bá à yọ̀,kí àwọn ọmọbìnrin aláìkọlà má baà dunnú.

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:17-21