2 Kíróníkà 33:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámónì jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó di ọba. Ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún méjì.

2 Kíróníkà 33

2 Kíróníkà 33:17-23