2 Kíróníkà 33:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánásè sinmi pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín sínú ààfin rẹ̀. Ámónì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba

2 Kíróníkà 33

2 Kíróníkà 33:18-23