2 Kíróníkà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí baba a rẹ̀ Mánásè ti ṣe. Ámónì sìn ó sì rú ẹbọ sí àwọn òrìṣà tí Mánásè ti ṣe.

2 Kíróníkà 33

2 Kíróníkà 33:14-25