2 Kíróníkà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó se ilé Olúwa náà lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú òkúta iyebíye. Góòlù tí ó lò jẹ́ wúrà párifáímù.

2 Kíróníkà 3

2 Kíróníkà 3:1-12