2 Kíróníkà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi igi fírì bo ilé yàrá ńlá náà ó sì bòó pẹ̀lú kìkì wúrà, ó sì ṣe é lọ́ṣọ̀ọ́ pẹ̀lú igi ọ̀pẹ àti àwòrán ẹ̀wọ̀n.

2 Kíróníkà 3

2 Kíróníkà 3:1-10