2 Kíróníkà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tẹ́ àjà ilé náà pẹ̀lú ìtí igi àti ìlẹ̀kùn ògiri àti àwọn ìlẹ̀kùn ilé Olúwa Pẹ̀lú wúrà, ó sì gbẹ́ àwòrán kérúbù sára ògiri.

2 Kíróníkà 3

2 Kíróníkà 3:1-15