2 Kíróníkà 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíjà sì di alágbára, ó sì gbé obìnrin mẹ́talá ní ìyàwó, ó sì bi ọmọkùnrin méjìlélógún, àti ọmọbìnrin mẹ́rìndinlógún.

2 Kíróníkà 13

2 Kíróníkà 13:12-22