2 Kíróníkà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìyókù ìṣe Ábíjà, àti ìwà rẹ̀, àti iṣẹ́ rẹ̀, a kọ wọ́n sínú ìwé ìtumọ̀ Ididì, wòlíì Ídò.

2 Kíróníkà 13

2 Kíróníkà 13:15-22