2 Kíróníkà 13:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ní Jéróbóámù kò sì tún ní agbára mọ́ ní ọjọ́ Ábíjà. Olúwa sì lù ú ó sì kú.

2 Kíróníkà 13

2 Kíróníkà 13:19-22