1 Tímótíù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí wọ́n má sì ṣe fiyèsí àwọn ìtàn-asán, àti ìtàn-ìran aláìlópin. Irú èyí máa ń mú iyàn jíjà wá dípò iṣẹ́ ìríjú Ọlọ́run èyí tí í ṣe ti ìgbàgbọ́.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:2-11