1 Tímótíù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo se rọ̀yín nígbàtí mò ń lọ sí Makedóníà, ẹ dúró ní Éfésù, kí ẹ lè dá àwọn ènìyàn kan lẹ́kun láti má ṣe kọ́ ni ní ẹ̀kọ́ èké mọ́

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:1-6