1 Tímótíù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sí Tímótíù ọmọ mi nínú ìgbàgbọ́:Oore-ọ̀fẹ́, àánú àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run baba àti Jésù Kírísítì Olúwa wa.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:1-8