1 Tímótíù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore-ọ̀fẹ́ Olúwa wa sì pọ̀ rékọjá pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́, tí ń bẹ nínú Kírísítì Jésù.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:4-20