1 Tímótíù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó sì yẹ fún ìtẹ́wọ́gbà, pé Jésù Kírísítì wá sí ayé láti gba ẹlẹ́sẹ̀ là; nínú àwọn ẹni tí èmi jẹ́ búburú jùlọ.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:8-16