1 Tímótíù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo tilẹ̀ jẹ́ asọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run rí, àti onínúnibíni àti ìkà ènìyàn: ṣùgbọ́n mo rí àánú gbà, nítorí tí mo ṣe é nínú àìmọ̀ àti àìgbàgbọ́.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:11-15