1 Tímótíù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹni tí ó fún mi ní agbára, àní Kírísítì Jésù Olúwa wa, nítorí tí ó kà mí sí olóòótọ́ ní yíyànmí sí iṣẹ́ rẹ̀;

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:9-14