1 Tẹsalóníkà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìdí èyí, nígbà tí ara mi kò gbà á mọ́, mo pinnu láti nìkan dúró ní ìlú Átẹ́nì.

1 Tẹsalóníkà 3

1 Tẹsalóníkà 3:1-7