1 Tẹsalóníkà 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rán Tímótíù, arákùnrin àti alábáṣiṣẹ́ pọ̀ wá, láti bẹ̀ yín wò. Mo rán an láti fún ìgbàgbọ́ yín lágbára àti láti mú yín lọ́kà le; àti kí ó má sì ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú, nínú ìṣòro tí ẹ ń là kọjá.

1 Tẹsalóníkà 3

1 Tẹsalóníkà 3:1-12