1 Tẹsalóníkà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn tí wọ́n pa Jésù Olúwa àti àwọn wòlíì, tí wọ́n sì tì wa jáde. Wọn kò ṣe èyí tí ó wu Ọlọ́run, wọ́n sì ṣe lòdì sí gbogbo ènìyàn

1 Tẹsalóníkà 2

1 Tẹsalóníkà 2:7-20