1 Tẹsalóníkà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nínú ìgbìyànjú wọn láti dá ìwàásù ìyìnrere dúró láàrin àwọn aláìkọlà kí wọn kí ó lè rí gbàlà. Ẹ̀sẹ̀ wọn ń di púpọ̀ síi lójoojúmọ́. Ṣùgbọ́n ní ìkẹyìn, ìbínú Ọlọ́run ti wá sórí wọn ní ìgbẹ̀yìn.

1 Tẹsalóníkà 2

1 Tẹsalóníkà 2:9-18