1 Tẹsalóníkà 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí, ẹ̀yin ara, ẹ jẹ́ àwòkọ́se àwọn ìjọ tí o wà ní Jùdíà jẹ. Bí a ti gbógun tì wọ́n, láti ọwọ́ àwọn ará ìlú wọn (àwọn Júù), bẹ́ẹ̀ ni a gbógun ti ẹ̀yin pàápàá láti ọ̀dọ̀ àwọn Júù,

1 Tẹsalóníkà 2

1 Tẹsalóníkà 2:4-20