1 Sámúẹ́lì 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì béèrè lọ́dọ̀ Olúwa fún un, ó sì fún un ní oúnjẹ́, kò sí fún un ni idà Gòláyátì ara Fílístínì.”

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:6-17