1 Sámúẹ́lì 22:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dóégì ara Édómù tí a fi jẹ olórí àwọn ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù, sì dáhùn wí pé, “Èmi rí ọmọ Jésè, ó wá sí Nóbù, sọ́dọ̀ Áhímélékì ọmọ Áhítúbì.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:2-17