1 Sámúẹ́lì 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì ránṣẹ́ pe Áhímélékì àlùfáà, ọmọ Áhítúbì àti gbogbo ìdílé baba rẹ̀, àwọn àlùfáà tí ó wà ni Nóbù: gbogbo wọn ni ó sì wá sọ́dọ̀ ọba.

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:9-17