1 Sámúẹ́lì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánà sì gbàdúrà pé:“Ọkàn mi yọ̀ sí Olúwa;Ìwọ agbára mi ni a sì gbé sókè sí Olúwa.Ẹnu mi sì gbòòrò lórí àwọn ọ̀ta mi,nítorí ti èmi yọ̀ ni igbala rẹ̀

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:1-3