1 Sámúẹ́lì 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà pẹ̀lú, èmi fí i fún Olúwa; ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀: nítorí tí mo ti béèrè rẹ̀ fún Olúwa.” Wọn si wólẹ̀ sin Olúwa nibẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:26-28